More

Mixtape of the Month

Mpmania Mix 39

Mpmania Mix 39

Brymo – “Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn)” [Audio, Lyrics]

Off the 9: Esan album, Brymo unveils the song, “Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn)” produced by Mikkyme Joses. Stream, buy, read the lyrics, mp3 download the song.

Brymo Ọkùnrin Mẹ́ta

Brymo Ọkùnrin Mẹ́ta

Brymo – Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn) (prod. Mikkyme Joses)

Lyrics

Gbemi san le
Ko mi sita
Fami lewu ya
Temi lorun pa
Eniyan lasan ni mo je
Mo fuye bi paper
Iji ja lodo
O gbemi lo soko

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

Emi ni imole
Olukunkun wo gbo lo
Mo fa lewuya
Mo te lorun pa
Eniyan lasan mi o je
Mo wiwo bi ésan
Emi ni iji to ja lodo
To gboba won lo soko

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Okunrin meta debi ti mo n lo

Written By

7shades of Weirdness! Media & Tech - Digital Creative...

View All Articles
L
C
Leave a Reply

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *