Brymo – “Tèmi Nì Tèmi” [Audio, Lyrics]

Date 2021-09-23

Category Lyrics, Naija Songs, New Music

Off His 9: Esan album, Brymo unveils another Mikkyme Joses-produced track, titled “Tèmi Nì Tèmi”. Stream, buy, read the lyrics, mp3 download.

Brymo Tèmi Nì Tèmi

Brymo Tèmi Nì Tèmi

Brymo – Tèmi Nì Tèmi (prod. Mikkyme Joses)

Lyrics

Ife mi dari jinmin
Omo de nse mi
Afarawe o se temi
Ka da duro ni mo wari
Moti so tele tele ri
Igboro o ma rerin ri
Ijakadi lomu nise
Ka ro′nri o b’opo sise
Bi nba fa a, won l′ole
Bi nba tule, won lo ro
Bi nduro won ma mu’ere
Bi nba sa won ni mo kere
Aba lo aba bo
Bo wunwon kan’para won
Owun ani lan nani
Temi ni temi
Awelewa f′ori jinmin
Mo lokaaka kin to debi
Riro mede o se temi
Nibi lile lan b′okunrin
Ife re sa loduro timi
Odudu ofunfun o pupa
Ife re sa lon’munu tumi
Ninu eerun at′ojo at’ailera
Bi nba fa a, won l′ole
Bi nba tule, won lo ro
Bi nduro won ma mu’ere
Bi nba sa won ni mo kere
Aba lo aba bo
Bo wunwon kan′para won
Owun ani lan nani
Temi ni temi
Aba lo aba bo
Temi lo je la’le oni o
Gbogbo igba ti o oba lo
Mo mo o pada wa

Written By

View All Articles

Creative Executioner! I take ideas from the subliminal to execution in the physical.

+Comment

Drop A Comment